1 Chronicles 3:5-8

5Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu:

Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bati-Ṣua ọmọbìnrin Ammieli.
6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.
Copyright information for YorBMYO